1 Kọ́ríńtì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa jẹ́ asiwèrè nítorí Kírísítì, ṣùgbọ́n ẹ̀yin jẹ́ ọlọ́gbọ́n nínú Kírísítì! Àwa jẹ́ aláìlera, ṣùgbọ́n ẹ̀yín jẹ́ alágbára! Ẹ̀yin jẹ́ ẹni àyẹ́sí, àwa jẹ ẹni ẹ̀gàn!

1 Kọ́ríńtì 4

1 Kọ́ríńtì 4:3-17