1 Kọ́ríńtì 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ṣe ló yẹ kí ènìyàn máa wò wá gẹ́gẹ́ bí ìranṣẹ́ àti ìríjú tí a fún ni oore-ọfẹ́ láti mọ Kírísítì tí a fún ní oore-ọ̀fẹ́ láti mọ àwọn ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run.

1 Kọ́ríńtì 4

1 Kọ́ríńtì 4:1-2