1 Kọ́ríńtì 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wàrà ni mo ti fi bọ́ yín, kì í ṣe oúnjẹ; nítorí ẹ kò í tí le gbà á nísinsin yìí náà, ẹ kò í tí le gbà a.

1 Kọ́ríńtì 3

1 Kọ́ríńtì 3:1-10