1 Kọ́ríńtì 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé ẹ̀yin kò tilẹ̀ mọ̀ pé tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́? Pé Ẹ̀mí Ọlọ́run ń gbé inú yín?

1 Kọ́ríńtì 3

1 Kọ́ríńtì 3:7-22