1 Kọ́ríńtì 2:15-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Ẹni tí ẹ̀mí ń ṣe ìdájọ́ ohun gbogbo, ṣùgbọ́n òun fúnra rẹ̀ ni a kò ti ọwọ́ ènìyàn dá lẹ́jọ́:

16. “Nítorí ta ni ó mọ ọkàn Olúwa,ti yóò fi máa kọ́ Ọ?”Ṣùgbọ́n àwa ní inú Kírísítì.

1 Kọ́ríńtì 2