1 Kọ́ríńtì 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni àwa ń wí, kì í e èyí tí a ń kọ nípa ọ̀rọ̀ ọgbọ́n ènìyàn, ṣùgbọ́n èyí tí Ẹ̀mí Mímọ́ fi ń kọ ènìyàn, èyí tí a ń fi ohun Ẹ̀mí wé ohun Ẹ̀mí.

1 Kọ́ríńtì 2

1 Kọ́ríńtì 2:8-15