1 Kọ́ríńtì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ti fi í hàn fún wa nípasẹ̀ Ẹ̀mi rẹ̀.Ẹ̀mí á máa wádìí ohun gbogbo, kódà àwọn àsírí Ọlọ́run tó jinlẹ̀ jùlọ.

1 Kọ́ríńtì 2

1 Kọ́ríńtì 2:5-11