1 Kọ́ríńtì 16:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n èmi yóò tọ̀ yin wá, nígbà tí èmí bá ti kọjá láàrin Makedóníà: nítorí èmi yóò kọjá láàrin Makedóníà.

1 Kọ́ríńtì 16

1 Kọ́ríńtì 16:1-12