1 Kọ́ríńtì 16:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ bí Tímótíù bá dé, ẹ jẹ́ kí ó wà lọ́dọ̀ yín láìbẹ̀rù: nítorí òun ń ṣé iṣẹ́ Olúwa, bí èmi pẹ̀lú ti ń ṣe.

1 Kọ́ríńtì 16

1 Kọ́ríńtì 16:4-14