1 Kọ́ríńtì 15:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹni erùpẹ̀ ti rí, irú bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn tí í ṣe erùpẹ̀: bí ẹni tí ọ̀run ti rí, irú bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn tí í ṣe tí ọ̀run.

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:39-58