1 Kọ́ríńtì 15:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó bá ṣe pé kìkì ayé yìí nìkan ní àwa ní ìrétí nínú Kírísítì, àwa jásí òtòsì jùlọ nínú gbogbo ènìyàn.

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:15-25