1 Kọ́ríńtì 14:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí àwọn wòlíì méjì tàbí mẹ́ta sọ̀rọ̀, ki àwọn ìyókù sì wòye ìtumọ̀ ohun tí a sọ.

1 Kọ́ríńtì 14

1 Kọ́ríńtì 14:20-31