1 Kọ́ríńtì 14:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, bí ìwọ bá sú ìre nípa ẹ̀mí, báwo ni ẹni tí ń bẹ ni ipò òpè yóò ṣe ṣe “Àmín” si ìdúpẹ rẹ, nígbà tí kò mọ ohun tí ìwọ́ wí?

1 Kọ́ríńtì 14

1 Kọ́ríńtì 14:7-19