1 Kọ́ríńtì 12:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó má ṣe sí ìyàtọ̀ nínú ara, ṣùgbọ́n kí àwọn ẹ̀yà ara le máa jẹ́ olùrànlọ́wọ́ fún ara wọn.

1 Kọ́ríńtì 12

1 Kọ́ríńtì 12:15-29