1 Kọ́ríńtì 12:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí gbogbo wọn bá sì jẹ́ ìkanṣoṣo nínú ẹ̀yà-ara, níbo ni ara yóò gbé wà.

1 Kọ́ríńtì 12

1 Kọ́ríńtì 12:18-25