1 Kọ́ríńtì 11:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n tí ẹ bá yẹ ara yín wò dáadáa, kí ẹ tó jẹ ẹ́, a kì yóò dá yín lẹ́jọ́.

1 Kọ́ríńtì 11

1 Kọ́ríńtì 11:26-34