1 Kọ́ríńtì 11:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòtọ́ láti ara ọkùnrin ni a ti yọ obìnrin jáde bẹ́ẹ̀ si ni ọkùnrin tipàsẹ obìnrin wa. Ṣùgbọ́n láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ohun gbogbo ti wà.

1 Kọ́ríńtì 11

1 Kọ́ríńtì 11:11-22