1 Kọ́ríńtì 10:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ṣè n gbìyanjú láti tẹ́ ẹnìkọ̀ọ̀kan lọ́rùn nínú gbogbo nǹkan tí mo bá ń ṣe láì wa ohun rere fún ara mi bí kò ṣe ti ènìyàn púpọ̀ kí ó lè ṣe é ṣe fún wọn láti le ní ìgbàlà.

1 Kọ́ríńtì 10

1 Kọ́ríńtì 10:23-33