1 Kọ́ríńtì 10:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ohun gbogbo ni o yẹ fún mi,” ṣùgbọ̀n kì í ṣe ohun gbogbo ni ó ní èrè. “Ohun gbogbo ni ó yẹ fún mi,” ṣùgbọ́n kì í ṣe ohun gbogbo ni ń gbe ni rò.

1 Kọ́ríńtì 10

1 Kọ́ríńtì 10:16-27