1 Kọ́ríńtì 10:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ẹni tí ó bá rò pé òun dúró, kí ó kíyèsára kí ó ma ba à subú.

1 Kọ́ríńtì 10

1 Kọ́ríńtì 10:11-17