1 Kọ́ríńtì 1:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí rẹ̀ ni ẹ̀yin ṣe wà nínú Kírísítì Jésù ẹni ti ó já sí ọgbọ́n fún wa láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run—èyi ń ni, òdodo, ìwà mímọ́ àti ìràpadà wa.

1 Kọ́ríńtì 1

1 Kọ́ríńtì 1:21-31