1 Kọ́ríńtì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oore-ọ̀fẹ́ àti àlàáfíà fún yín láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wa àti Olúwa wa tí í ṣe Jésù Kírísítì.

1 Kọ́ríńtì 1

1 Kọ́ríńtì 1:1-12