1 Kọ́ríńtì 1:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ará, ẹ kíyèsí ohun tí nígbà tí a pè yín. Bí ó ti ṣe pé, kì í ṣe ọ̀pọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n ènìyàn nípa ti ara, kí í ṣe ọ̀pọ̀ àwọn alàgbà, kì ì ṣe ọ̀pọ̀ àwọn ọlọ́lá ni a pè.

1 Kọ́ríńtì 1

1 Kọ́ríńtì 1:22-31