ṣùgbọ́n sí àwọn tí Ọlọ́run tí pè, àti àwọn Júù àti àwọn Gíríkì, Kírísítì ni agbára Ọlọ́run, àti ọgbọ́n Ọlọ́run.