1 Kọ́ríńtì 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú mi dún púpọ̀ pé èmi kò tẹ ẹnikẹ́ni nínú yín bọmi yàtọ̀ sí Kírísípù àti Gáíù.

1 Kọ́ríńtì 1

1 Kọ́ríńtì 1:8-24