1 Kíróníkà 9:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hútayì ọmọ Ámíhúdì, ọmọ Ómírì, Ọmọ Ímírì, ọmọ Bánì, ìran ọmọ Fárésì ọmọ Júdà.

1 Kíróníkà 9

1 Kíróníkà 9:1-14