1 Kíróníkà 9:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nérì jẹ́ baba Kíṣì, Kíṣì baba a Ṣọ́ọ̀lù, àti Ṣọ́ọ̀lù baba a Jónátanì, àti Málíkíṣuà, Ábínádábù àti Éṣí-Bálì.

1 Kíróníkà 9

1 Kíróníkà 9:37-43