1 Kíróníkà 9:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ará Léfì tí a sọ ní Mátítíhíà, àkọ́bí ọmọkùnrin Ṣálúmì ará kórà ni a yàn sí ìdí dídín àkàrà ọrẹ.

1 Kíróníkà 9

1 Kíróníkà 9:27-32