1 Kíróníkà 9:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn mìíràn ni a yàn láti bojútó ohun èlò àti gbogbo ohun èlò ilé tí a yà sọ́tọ̀ fún Ọlọ́run, àti ìyẹ̀fun àti ọtí èso àjàrà àti òróró náà, tùràrí àti tùràrí òlóòórìn dídùn.

1 Kíróníkà 9

1 Kíróníkà 9:25-35