1 Kíróníkà 9:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísìnsìn yìí, àwọn tí ó kọ́ kọ́ tún tẹ̀dó lórí ohun ìní wọn ní ìlú wọn ni díẹ̀ nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà, àwọn ará Léfì àti àwọn Ìránsẹ́ ilé Olúwa.

1 Kíróníkà 9

1 Kíróníkà 9:1-4