1 Kíróníkà 8:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásì jẹ́ bàbá a Jéhóádá, Jéhóádá jẹ́ baba a Álémétì Áṣíméfétì àti Ṣímírì, Ṣímírì sì jẹ́ baba a Móṣà.

1 Kíróníkà 8

1 Kíróníkà 8:26-40