1 Kíróníkà 8:10-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Jéúṣì Ṣákíà àti Mírímà. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin Rẹ̀, olórí àwọn ìdílé.

11. Nípaṣẹ̀ Húṣímù ó ní Ábítúbù àti Élípálì.

12. Àwọn ọmọ Élípálì:Ébérì, Míṣámì, Ṣémédù (ẹni tí ó kọ́ Ónò àti Lódì pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká Rẹ̀.)

13. Pẹ̀lú Béríà àti Ṣémà, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Áíjálónì àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gátì kúrò.

14. Áhíò, Ṣásákì Jérémílò,

15. Ṣébádíà, Árádì, Édérì

16. Míkáélì Íṣífà àti Jóhà jẹ́ àwọn ọmọ Béríà.

1 Kíróníkà 8