1 Kíróníkà 7:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìtàn ìdílé wọn láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn tí a kọ lẹ́sẹsẹ jẹ́ ti àwọn olórí ìdílé àti ẹgbẹ̀rún-ní ọ̀nà ogún-ó-lé nígba (20,200) Ọkùnrin alágbára

1 Kíróníkà 7

1 Kíróníkà 7:7-12