1 Kíróníkà 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ìbátan tí ó jẹ́ alágbára akọni àwọn ọkùnrin tí ó jẹ́ ti àwọn ìdílé Ísákárì, bí a ti tò ó lẹ́sẹsẹ nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́tadínlàádórin ni gbogbo Rẹ̀.

1 Kíróníkà 7

1 Kíróníkà 7:1-15