1 Kíróníkà 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Máákà, ìyàwó Mákírì bí ọmọkùnrin kan. Ó sì sọ orúkọ Rẹ̀ ní Pérésì. Ó sì pe arákùnrin Rẹ̀ ní Ṣéréṣì, àwọn ọmọ Rẹ̀ sì ní Úlámù àti Rákémù.

1 Kíróníkà 7

1 Kíróníkà 7:14-23