1 Kíróníkà 6:62 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ìran ọmọ Géríṣómù, sí ìdílé ni a pín ìlú mẹ́talá fún láti ẹ̀yà àwọn ẹ̀yà Íṣákárì, Áṣérì àti Náfítalì, àti láti apá ẹ̀yà Mánásè tí ó wà ní Básánì.

1 Kíróníkà 6

1 Kíróníkà 6:60-71