1 Kíróníkà 6:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn Léfì ẹgbẹ́ wọn ni wọn yan àwọn iṣẹ́ yókù ti Àgọ́ fún, èyí tí í ṣe ilé Ọlọ́run.

1 Kíróníkà 6

1 Kíróníkà 6:42-49