1 Kíróníkà 6:38-46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

38. ọmọ Íṣíhárì, ọmọ Kóhátìọmọ Léfì, ọmọ Ísírẹ́lì;

39. Hémánì sì darapọ̀ mọ́ Ásátì, ẹni tí Ó sìn ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀:Ásátì ọmọ bérékíáhì, ọmọ Ṣíméà,

40. Ọmọ Míkáélì, ọmọ Bááséíáhì,ọmọ Málíkíjáhì

41. Ọmọ Étínì,ọmọ Ṣéráhì, ọmọ Ádáyà,

42. Ọmọ Étanì, ọmọ Ṣímáhì,ọmọ Ṣíméhì,

43. Ọmọ Jáhátì,ọmọ Gérísíónì, ọmọ Léfì;

44. láti ìbákẹ́gbẹ́ wọn, àwọn ará Mérárì wà ní ọwọ́ òsì Rẹ̀:Étanì ọmọ Kísì, ọmọ Ábídì,ọmọ Málúkì,

45. Ọmọ Háṣábíáhìọmọ Ámásáyà, ọmọ Hítíkíáhì,

46. Ọmọ Ámíṣì ọmọ Bánì,ọmọ Ṣémérì,

1 Kíróníkà 6