1 Kíróníkà 6:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A kó Jéhósádákì lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Júdà àti Jérúsálẹ́mù kúrò ní ìlú nípaṣẹ̀ Nebukadinésárì.

1 Kíróníkà 6

1 Kíróníkà 6:9-23