1 Kíróníkà 5:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti Bélà ọmọ Ásásì ọmọ Ṣémà, ọmọ Jóẹ́lì tí ń gbé Áróérì àní títí dé Nébò àti Baaliméónì.

1 Kíróníkà 5

1 Kíróníkà 5:1-12