1 Kíróníkà 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Béérà ọmọ Rẹ̀, tí Tígílátì-pílínésérì ọba Ásíríà kó ní ìgbékùn lọ: ìjòyè àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ni òun jẹ́.

1 Kíróníkà 5

1 Kíróníkà 5:4-15