1 Kíróníkà 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti àwọn arákùnrin wọn ti ilẹ̀ àwọn baba wọn ní:Míkáélì, Mésúlímù Ṣébà, Jóráì, Jákánì, Ṣíà àti Hébérì méje.

1 Kíróníkà 5

1 Kíróníkà 5:12-17