1 Kíróníkà 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àkọ́bí Ísírẹ́lì. (Nítorí òun ni àkọ́bí; ṣùgbọ́n, bí ó ti ṣe pé ó ba ẹní baba Rẹ̀ jẹ́, a fi ogún ìbí Rẹ̀ fún àwọn ọmọ Jóṣẹ́fù ọmọ Ísírẹ́lì: a kì yóò sì ka ìtàn ìdílé náà gẹ́gẹ́ bí ipò ìbí.

1 Kíróníkà 5

1 Kíróníkà 5:1-3