1 Kíróníkà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jábésì sì ní olá ju àwọn ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ ọkùnrin lọ. Ìyá Rẹ̀ sì sọ ọ́ ní Jábésì wí pé, “Mo bí i nínú ìpọ́njú.”

1 Kíróníkà 4

1 Kíróníkà 4:1-14