1 Kíróníkà 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nárà sì bí Áhúsámù, Héférì Téménì àti Háhásítarì. Àwọn wọ̀nyí sì ni àwọn ọmọ Nátà.

1 Kíróníkà 4

1 Kíróníkà 4:1-8