1 Kíróníkà 4:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọkùnrin tí a dárúkọ lókè yìí àwọn ni ìjòyè ìdílé wọn. Àwọn ìdílé sì pọ̀ síi gidigidi,

1 Kíróníkà 4

1 Kíróníkà 4:34-43