1 Kíróníkà 4:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti gbogbo ìletò tí ó wà ní agbégbé àti gẹ́gẹ́ bí ó ti dé Bálì Àwọn wọ̀nyí ni ibùgbé wọn, wọ́n sì pa ìwé ìtàn ìdílé mọ́.

1 Kíróníkà 4

1 Kíróníkà 4:27-38