1 Kíróníkà 4:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn sì ni amọ̀kòkò tí ń gbé ní Nítaímù àti Gédérà; wọ́n sì dúró níbẹ̀ wọ́n sì ń sisẹ́ fún ọba.

1 Kíróníkà 4

1 Kíróníkà 4:17-25