1 Kíróníkà 4:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Réáíà ọmọ Ṣóbálì ni baba Jáhátì, àti Jáhátì baba Áhúmáyì àti Láhádì. Àwọn wọ̀nyí ni ẹ̀yà ará Ṣórà.

1 Kíróníkà 4

1 Kíróníkà 4:1-6