1 Kíróníkà 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Méónótaì sì ni baba Ófírà.Ṣéráíà sì jẹ́ baba Jóábù,baba Géhárásínù. A pè báyìí nítorí àwọn ènìyàn àwọn onísọ́nà niwọ́n.

1 Kíróníkà 4

1 Kíróníkà 4:4-20